Nnanna Ikpo
Ìrísí
Nnanna Ikpo jẹ́ ònkọ̀wé ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1] Ó di gbajúmọ́ fún ìwé rẹ̀ tí ó pe akòrí rẹ̀ ní Fimí Sílẹ̀ Forever ní ọdún 2017. Wọ́n yan ìwé yí fún àmì-ẹ̀yẹ Lambda Literary Award níbi Gay Fiction níbi ìdíje 30th Lambda Literary Awards ní ọdún 2018.[2]