Nneka Ezeigbo
Ìrísí
No. 33[1] – Robert Morris Colonials women's basketball | |
---|---|
Center | |
Personal information | |
Born | Ewing, New Jersey |
Listed height | 6 ft 2 in (1.88 m) |
Career information | |
High school | Notre Dame High School |
Nneka Ezeigbo jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó ń gbá bakẹtibọ́ọ̀lù. Arábìnrin jẹ́ ọkàn lára àwọn Òṣeré márùn-ún tí orúkọ rẹ yóò yọ ní Roll Academic Honor Roll NEC fún ìgbà mẹ́rin, Òṣèré kan ṣoṣo nínú àwọn ètò ìtàn-akọọlẹ láti kópa nínú mẹ́rin àwọn ẹgbẹ́ aṣáájú ìgbà déédéé NEC mẹrin.
Ìgbésí ayé ibẹ̀rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìyá rẹ jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Jamaika tí bàbá rẹ̀ jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Nàìjíríà. Tí ó dàgbà ní Ilu Ewing, New Jersey, bàbá rẹ̀ kú nípa àrùn kásà nígbà tí ó jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ ní ilé-ìwé Ile-iwe giga Notre Dame . Ó ní àwọn àbúrò méjì tí orúkọ wọ́n jẹ́ Chukwuka (Ẹ̀gbọ́n obìnrin tí ó gbá bakẹtibọ́ọ̀lù ní Yunifasiti Marshall àti Obi ( Àbúrò ọkùnrin tí o ń gbá bọ́ọ̀lù ní Gannon lọ́wọ́lọ́wọ́).
Àwọn ìtọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Women's Basketball". Robert Morris University Athletics. 2020-10-19. Retrieved 2024-03-16.