Nnenna Egwuekwe

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Nenny B
Nenny B MTV Base Africa 4th July 2019 Cropped 009.jpg
Ọjọ́ìbíNnenna Egwuekwe
Oṣù Kẹ̀sán 22, 1992 (1992-09-22) (ọmọ ọdún 28)
Lagos State, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ẹ̀kọ́Chukwuemeka Odumegwu Ojukwu University
University of Wollongong
Ìgbà iṣẹ́2007–present
Ọmọ ìlúImo State, Nigeria

Nnenna Egwuekwe (bíi ni ọjọ́ kẹji lélógún oṣù kẹsàn-án ọdún 1992) tí orúkọ inagi rẹ jẹ Nenny B je ọmọ Nàìjíríà, ó sì jẹ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ fún MTV Base Africa.[1] [2][3]

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Nnenna sì ìpínlè Èkó. Ó jẹ́ omo ìpínlè Imo ni Naijiria.[4] Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Aloysius Primary School ni Abuja fún ẹ̀kọ́ ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ rẹ̀. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Chukwuemeka Odumegwu Ojukwu University ni ibi tí ó ti gboyè nínú eko èdè gẹ̀ẹ́sì àti Mass Communication. Ó tesiwaju nínú ẹ̀kọ́ rẹ ni University of Wollongong.[5]

Iṣẹ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ó bẹ́ẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ni odun 2007 ni 2007 Kora Awards ni igba ti ó gbé 50 Cent. Ní ọdún 2009, ó sì ṣé pelu Africa Independent Television, AIT, gẹ́gẹ́ bíi olùkọ́ ṣe nínú ètò Matter Arising . Ó kò pá nínú ètò X-Factor West Africa àti Star the Winner is ni ọdún 2014.[6] Ó darapọ̀ mọ́ News Agency of Nigeria (NAN) gẹ́gẹ́ bíi oniroyin. Ní ọdún 2014, ó darapọ̀ mọ́ Hot 98.3 Fm gẹ́gẹ́ bí atọkun fún ètò Daily Drive Time Show àti Battle of The Sexes. Ní ọdún 2017, Radio Magazine fi Nenny B ṣi ojúewé àkọ́kọ́ wọn, wọn si pe ni ìkan laarin awọn agbóhùnsáfẹ́fẹ́ to tayọ julọ ni Nàìjíríà. Ó ti ṣe atọkun fún àwọn ètò bíi My Big Nigerian Wedding, La Belle Africa, Trace Afrobeat Show, Johnnie Walker Jazz & Whiskey Night, AMVCA After Party, Jamrock, Celeb Living. Ní oṣù kọkànlá ọdún 2017, ní Ilé iṣẹ́ Nkataa fi ṣe aṣojú fún wọn.[7] Láti ọdún 2018 ni ó tí ń sì ṣe fún MTV Base Africa gẹ́gẹ́ bí VJ.[8]

Ẹ̀bùn[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Year Event Prize Result Ref
2019 Nigeria Hype Awards TV Personality of the Year Gbàá [9]
Scream All Youth Awards Fast Rising TV Personality Wọ́n pèé [5]
2017 Nigerian Broadcasters Merit Awards Best Radio Show Wọ́n pèé [5]
2016 Exquisite Lady of the Year Female On-Air Personality Wọ́n pèé [10]
2015 Peace Achievers Awards Female On-Air Personality Gbàá [5]
Nigerian Broadcasters Merit Awards Sexiest Female On-Air Personality Wọ́n pèé [11]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 1. Onuoha, Chris (9 December 2019). "Nenny B standing tall against odds". Vanguard Nigerian Newspaper. https://www.vanguardngr.com/2019/12/nenny-b-standing-tall-against-odds. 
 2. "Falz, Skibii, others thrill fun-seekers at MTV Base's anniversary party". Premium Times. 7 March 2019. https://www.premiumtimesng.com/entertainment/music/318227-falz-skibii-others-thrill-fun-seekers-at-mtv-bases-anniversary-party.html. 
 3. Ogala, George (24 January 2019). "Nigeria: New Season of MTV Base 'Celeb Living' Debuts". AllAfrica.com. https://allafrica.com/stories/201901240505.html. 
 4. "Nenny B – Biography". Paragon Page. 16 January 2019. https://paragonpage.com.ng/nenny-b-biography. 
 5. 5.0 5.1 5.2 5.3 "Biography of Nenny B, Award Winning TV Presenter". Modern Ghana. 9 December 2019. https://www.modernghana.com/nollywood/35625/biography-of-nenny-b-award-winning-tv-presenter.html. 
 6. "Jackson Okoro emerges the Episode 10 Champion as Star the Winner Is enters its Semi-Finals!". BellaNaija. 23 September 2014. https://www.bellanaija.com/2014/09/jackson-okoro-emerges-the-episode-10-champion-as-star-the-winner-is-enters-its-semi-finals. 
 7. "WOW!!! Abuja Popular OAP Nenny B Signs Mega Ambassadorial Contract With Nkataa Company (Photos)". Naijaloaded. 20 November 2017. https://www.naijaloaded.com.ng/entertainment/wow-abuja-popular-oap-nenny-b-signs-mega-ambassadorial-contract-nkataa-company-photos. 
 8. "To be recognised is truly a blessing –Nenny B". The Nation Nigerian Newspaper. 11 May 2019. https://thenationonlineng.net/to-be-recognised-is-truly-a-blessing-nenny-b. 
 9. Abulude, Samuel (12 May 2019). "Nigeria Hypes Awards: Nenny B Bags ‘TV Personality Of The Year’ Award". Leadership Nigerian Newspaper. https://leadership.ng/2019/05/12/nigeria-hypes-awards-nenny-b-bags-tv-personality-of-the-year-award. 
 10. "The 2016 Exquisite Lady of the Year (ELOY) Awards – Seyi Shay, Tiwa Savage, Omoni Oboli, Adesua Etomi & Many More Outstanding Women Nominated". BellaNaija. 4 October 2016. https://www.bellanaija.com/2016/10/the-2016-exquisite-lady-of-the-year-eloy-awards-seyi-shay-tiwa-savage-omoni-oboli-adesua-etomi-many-more-outstanding-women-nominated. 
 11. Popoola, Kazeem (25 January 2016). "Finally! Here Is Authentic List Of Nominees For NBMA 2015". The Nigerian Voice. https://thenigerianvoice.com/news/204198/finally-here-is-authentic-list-of-nominees-for-nbma-2015.html.