Nolene Conrad
Ìrísí
Òrọ̀ ẹni | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Ọjọ́ Kẹrìndínlọ́gbọ̀n Osù Keje Ọdún 1985 (Ọdún Mẹ́rìndínlógójì) |
Sport | |
Orílẹ̀-èdè | South Africa |
Erẹ́ìdárayá | [Eré Sísá ti ọ̀nà jínjìn] |
Nolene Conrad tí a bí ní Ọjọ́ Kẹrìndílọ́gbọ̀n Osù Keje Ọdún 1985 jẹ́ asáré -ọ̀nà tó jìnà ti ilẹ̀ South Africa kan .
Ní ọdún 2013, ó kópa nínú ìdíje àwọn obìnrin àgbà ní IAAF àgbáyé jákè jádò orílẹ̀ èdè ti ọdún 2013 tí ó wáyé ní Bydgoszcz, Poland. Ó parí pẹ̀lú ipò kọkàndínlọ́gọ́rin. [1] Ní ọdún 2015, ó kópa nínú ìdíje àwọn obìnrin àgbà ní IAAF àgbáyé jákè jádò orílẹ̀ èdès ti ọdún 2015 tí ó wáyé ní Guiyang, China. Ó sì parí pẹ̀lú ipò kẹrìndínlógójì. [2]
Ní ọdún 2018, o kópa nínú ìdíje eré sísá ìdajì eré tí ó jìnà ti àwọn obìnrin ní IAAF World Half Marathon Championships ti ọdún 2018 tí ó wáyé ní Valencia, Spain. O parí pẹ̀lú ipò karùndínlọ́gbọ̀n. [3]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedsenior_women_race_iaaf_world_cross_country_championships_2013
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedsenior_women_race_iaaf_world_cross_country_2015
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedwomen_half_marathon_iaaf_championships_2018