Nomzamo Mbatha

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Nomzamo Nonzwakazi Mbatha
Ọjọ́ìbíNomzamo Nxumalo Mbatha
13 Oṣù Keje 1990 (1990-07-13) (ọmọ ọdún 33)
KwaMashu Township, KwaZulu Natal, South Africa
Ẹ̀kọ́Bechet High School
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of Cape Town
Iṣẹ́Actress and UNHCR goodwill ambassador
Ìgbà iṣẹ́2012-present
ẸbíZamani Mbatha (brother)

Nomzamo Nxumalo Mbatha (bíi ni ọjọ́ kẹtàlá oṣù keje ọdún 1990) jẹ́ òṣèré, agbóhùnsáfẹ́fẹ́, ọlọ́jà àti ajìjàgbara ni orílẹ̀ èdè South Áfríkà.[1]

Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bíi ni ọjọ́ kẹtàlá oṣù keje ọdún 1990 sì ìlú KwaMashu.[2] Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ tí Rippon primary school ni Durban àti Bechet High School. Ní ọdún 2018, ó gboyè jáde nínú ìmò ìṣirò owó láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of Cape Town.

Iṣẹ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ó bẹ̀rẹ̀ eré ṣíṣe pelu eré Isibaya. Ó ṣe atọkun fun ètò Holiday swap ni ọdún 2014 lórí South African Broadcasting Corporation. Ní ọdún 2015, ó ṣe aṣojú fún Neutrogena.[3] Ní ọdún 2019, ó kopa nínú eré Coming 2 America[4]. Ní ọdún 2018, ilé iṣẹ́ OkayAfrica Digital Media ní pé ó wà láàrin àwọn OkayAfrika 100 Women Honorees.[5] Wọn yàán fún African Movie Academy Awards gẹ́gẹ́ bíi òṣèré to dára jù lọ fún ipá Moratiwa tí ó kó nínú eré Tell Me Sweet Something ni ọdún 2015.[6][7]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. CUT FM Radio (10 November 2018). "Nomzamo Mbatha Biography". Bloemfontein: 105.8 CUT FM Radio Station. Archived from the original on 19 April 2021. Retrieved 13 January 2019. 
  2. Globefeed.com (13 January 2019). "Distance between Durban, eThekwini, Kwazulu Natal, ZAF and KwaMashu, eThekwini Metropolitan Municipality, KwaZulu-Natal, ZAF". Globefeed.com. Retrieved 13 January 2019. 
  3. Ayanda Molefe (23 June 2015). "Nomzamo Mbatha has every reason to smile as it’s just been announced that she is the new face of Neutrogena". Elle Magazine South Africa. Archived from the original on 12 April 2016. Retrieved 15 January 2019.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. Ramos, Dino-Ray (July 9, 2020). "CAA Signs 'Coming 2 America' Actress Nomzamo Mbatha". Deadline Hollywood. Retrieved July 13, 2020. 
  5. OkayAfrica (23 March 2018). "100 Women: Nomzamo Mbatha Wants Black Women to Know That They "Don't Have to Be Polite"". Okayafrica.com. Retrieved 13 January 2019. 
  6. Channel 24 (13 June 2016). "Nomzamo slays at the African Movie Academy Awards". Johannesburg: Channel 24 South Africa. Retrieved 13 January 2019. 
  7. Daily Sun Reporter (2 June 2016). "Nomzamo Mbatha nominated for AMAA!". Daily Sun. Johannesburg. Retrieved 13 January 2019.