Jump to content

Noureddine Bouyahyaoui

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Noureddine Bouyahiaoui
Personal information
Ọjọ́ ìbí7 Oṣù Kínní 1955 (1955-01-07) (ọmọ ọdún 69)
Ibi ọjọ́ibíMorocco
Playing positionDefender (association football)
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
KAC Kenitra
National team
Morocco national football team
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals).

Noureddine Bouyahiaoui (Ni èdè larubawa: نور الدين البويحياوي) ni a bini ọjọ keje, óṣu January, ọdun 1955 jẹ agbabọọlu afẹsẹgba to ṣèrè gẹgẹbi defender fun órilẹ ede Morocco[1][2][3][4].

Elere naa ṣèrè fun KAC Kenitra. Ni ọdun 1986, Noureddine kopa ninu Cup Agbaye ti FIFA[5][6].

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. MATCHES OF N. BOUYAHYAOUI
  2. National Team Appearances of Noureddine Bouyahyaoui
  3. Noureddine Bouyahyaoui
  4. Bouyahyaoui's career statistics
  5. CAREER DETAILS
  6. 1986 FIFA World Cup Mexico