Jump to content

Nyeri Museum

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Nyeri Museum
Building
LocationNyeri, Kenya
Coordinates0°26′24″S 36°57′51″E / 0.439980°S 36.964068°E / -0.439980; 36.964068Coordinates: 0°26′24″S 36°57′51″E / 0.439980°S 36.964068°E / -0.439980; 36.964068

Nyeri Museum (Swahili: Makumbusho ya Nyeri) jẹ́ musíọ́mù kan tí ó wà ní Nyeri, orílẹ̀ èdè Kenya. Musíọ́mù náà wà fún ìgbé lárugẹ ìtàn Kenya àti àṣà Kikuyu.

Àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Nyeri Native Council nínú ilé tí ó padà di musíọ́mù náà.

Wọ́n kọ́ musíọ́mù náà ní ọdun 1924 gẹ́gẹ́ bi ilé ẹjọ́, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí ń lòó láti pari ẹjọ́ ní ọdún 1925.[1] Ní àwọn ọdún 1970s, lẹyìn tí wọ́n kọ́ ile ẹjọ́ Nyeri Law Courts, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí ń lo ilé musíọ́mù yìí fún àwọn ìpàdé Nyeri Municipal Council.[2] Ní ọdún 1997, wọ́n fa ilé ìwé náà lé National Museums of Kenya lọ́wọ́.[3] Nígbà náà, National Museums of Kenya gbèrò láti tún musíọ́mù ṣe.[4] Ní ọdún 2001, wọ́n sọ musíọ́mù náà di ti ìjọba.[5]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Nyeri Museum – National Museums of Kenya" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-06-21. 
  2. Komu, Nicholas (2019-06-11). "Former 'pregnancies court' becomes cherished monument". Nation.Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-08-18.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "Nyeri County Weekly Review Issue No. 43" (PDF). 2020. Retrieved 2021-08-18.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. Wamathai, James (2014-10-02). "Museums, vibrating cars and other Central Kenya stories". HapaKenya (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-06-21. 
  5. "Discover Kenya's History at its First Courtroom". Google Arts & Culture (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-06-21.