Oúnjẹ Dabo Kolo
Dabo kolo ( ዳቦ ቆሎ ) | |
Region or state | Ethiopia, Eritrea, Democratic Republic of the Congo |
---|---|
Main ingredients | Flour, milk, barley |
Other information | For snacking or festivity |
Àdàkọ:Wikibooks-inline
|
Dabo kolo (Amharic: ዳቦ ቆሎ (d'abo kolo), Oromo: Boqqolloo daabboo) jẹ́ oúnjẹ orílẹ̀ èdè Ethiopia àti Eritrea. Èyí tí ó jẹ́ ìpanu aláta.[1][2][3] Dabo kolo túmọ̀ sí búrẹ́dì alágbàdo nínú èdè Amharic, dabo túmọ̀ sí búrẹ́dì, àti kolo tí ó túmọ̀ sí àgbàdo tàbí barley, chickpea, èso sunflower, àti ẹ̀pà sísun.[4]
Búrẹ́dì Kolo èyí tí a yí mọ́ inú bébà jẹ́ èyí tí wọ́n sáábà máa ń tà ní àwọn ilé ìtajà kéékèèké àti ní àwọn ojú òpópónà. Ní ìgbà mìíràn a le fi oyin sí inú dabo kolo láti mú un dùn. Wọ́n ka Dabo kolo sí oúnjẹ àwọn Congolese.[5] Ẹ̀yà oúnjẹ dabo kolo tí kò wọ́pọ̀ ni èyí tí a ṣe láti ara ẹ̀wà coffee.[6]
Àwọn Àjọ̀dún
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Dabo kolo jẹ́ ọ̀kan pàtàkì nínú gbogbo àwọn oúnjẹ tí wọ́n máa ń lò nígbà àjọ̀dún ọdún tuntun tí àwọn ará ilẹ̀ Ethiopia. Ó jẹ́ oúnjẹ ìbílẹ̀ tí à ń pè ní Beta Israel máa ń jẹ nígbà tí wọ́n bá ń ṣe àjọyọ̀ sábáàtì nínú ìtàn àwọn Jews ní orílẹ̀ èdè Ethiopia. [7]
Wò pẹ̀lú
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Dabo Kolo. Traditional Snack From Ethiopia". www.tasteatlas.com. Retrieved 27 May 2021.
Dabo kolo is Ethiopian snack with a spicy flavor and crunchy texture, consisting of flour, sugar, salt, water, butter, and berberé spices.
- ↑ Àdàkọ:YouTube. Transliterated Amharic: Yemit’adi dabo k’olo āserari. A lady explains how to prepare Dabo kolo with ingredients of turmeric and berbere for colour, sugar, oil, milk, water and wheat flour. Video of 45m 56s. Retrieved 27 May 2022.
- ↑ Àdàkọ:YouTube. Ingredients are hot water, salt, sugar, oil, and colouring. The dough is kneaded to a long roll, then cut to small pieces of sweetcorn size, and fried in hot oil for 3 minutes. Video of 1m 51s. Retrieved 27 May 2022.
- ↑ "Kolo. Traditional Snack From Ethiopia - TasteAtlas". www.tasteatlas.com. Retrieved 27 May 2022.
Kolo is a traditional Ethiopian snack consisting of a combination of roasted grains such as barley, chickpeas, and sunflower seeds.
- ↑ Kanjilal, Sahana (26 November 2019). "Top 9 Congolese Foods for Your Appetite". flavorverse.com. Retrieved 27 May 2022.
- ↑ The Hans India (15 January 2018). "Telangana International Sweets Festival proves to be a big hit". www.thehansindia.com. Retrieved 27 May 2022.
- ↑ Marks, Gil (1996). The World of Jewish Cooking. New York, NY: Simon & Schuster. p. 273. ISBN 9780684835594. https://books.google.com/books?id=Ux2lGKCKVPYC&q=The:+World+of+Jewish+Cooking.
Àdàkọ:Eritrea-stub Àdàkọ:Ethiopia-cuisine-stub Àdàkọ:DRCongo-stub Àdàkọ:RepublicoftheCongo-stub