OJB Jezreel
Ìrísí
OJB Jezreel. | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Babatunde Augustine Okungbowa Oṣù Keje 4, 1966 Surulere, Lagos |
Aláìsí | June 14, 2016 Isolo, Lagos | (ọmọ ọdún 49)
Orúkọ míràn | Jiggaman, DJ Young, Bishop |
Àwọn ọmọ | 7 including Ayokunle Okungbowa (Ayo Jezreel)[1] |
Musical career | |
Irú orin | |
Occupation(s) | Musician, singer, songwriter, record producer |
Instruments |
|
Years active | 1986-2016 |
Labels | Kennis Music, Amazing Records |
Babatunde Okungbowa (4 July 1966 – 14 June 2016), ti gbogbo ènìyàn mọ̀ nípasẹ orukọ ipele rẹ̀ OJB Jezreel tàbí OJB, jẹ́ akọrin Nàìjíríà, akọrin àti olupilẹṣẹ igbasilẹ. Ó kú ní ojọ́ kerinlà oṣù kẹfà Ọdún 2016. Òní àrùn kídìrìín.