Jump to content

Obianuju Ekeocha

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Obianuju Ekeocha
Ọjọ́ìbí1979 (ọmọ ọdún 44–45)
Owerri, Nigeria
Ẹ̀kọ́Hematology
Biomedical science
Iléẹ̀kọ́ gíga
Iṣẹ́Author
Scientist
Notable workOpen Letter to Melinda Gates[1]

Obianuju Ekeocha /θj/, tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí Uju (a bi ní odun 1979), jẹ́ onímọ̀ Sáyẹ́nsì ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà tí ó ń gbé ní Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan.[2] Òun ni ọ̀lùdásílẹ̀ àti ààrẹ "Culture of Life Africa".[3][4]

Ekeocha ń gbé ní orílẹ̀ èdè Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan[5] ẹ̀ka ibi tí ó ti ń síse ni ẹ̀ka àwọn tí ó ń wo ẹ̀jẹ̀ fún àìsàn, kòkòrò àti àwọn nkan míràn. Ní ọdún 2016, wón fun ní isẹ́ sí ilé ìwòsàn ní Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan. Ó jẹ́ ara ìjọ Kátólíìkì làti Ìpìlẹ̀ ṣẹ̀ṣẹ̀ ayé rẹ̀ nígbà tí ó wà ní Nàìjíríà.[6]

Obianuju lọ ilé-ìwé Federal Government Girls' College ti Owerri, kí ó tó tẹ̀ ẹ̀kọ́ rẹ̀ síwájú ní Yunifásítì ilẹ̀ Nàìjíríà, Nsukka, níbi tí ó ti gba àmì ẹyẹ Bachelor nínú ìmò Microbiology. Lẹ́yìn èyí ó lọ orílè-èdè Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan láti gbà àmì ẹyẹ master nínú ìmò Biomedical scienceYunifásítì East London.

  1. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named kilgus191024
  2. "Obianuju Ekeocha". Catholic Answers. Retrieved 2020-11-19. 
  3. "Obianuju Ekeocha". Acton University (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-11-19. 
  4. "Obianuju Ekeocha: Founder & President of Culture of Life Africa". Culture of Life Africa. Retrieved 2021-02-12. 
  5. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :02
  6. Feingold, Sophia (April 27, 2016). "Pro-Life in Africa: ‘What We Hold in Common Is This Value for Family’. Obianuju Ekeocha, founder and president of Culture of Life Africa, shares her continent’s long-held values.". National Catholic Register. http://www.ncregister.com/news/pro-life-in-africa-what-we-hold-in-common-is-this-value-for-family-990wcul7.  Retrieved February 24, 2022.