Ochai Agbaji
Ìrísí
Agbaji in 2022 | |
No. 30 – Utah Jazz | |
---|---|
Position | Shooting guard |
League | NBA |
Personal information | |
Born | 20 Oṣù Kẹrin 2000 Milwaukee, Wisconsin, U.S. |
Listed height | 6 ft 5[1] in (1.96 m) |
Listed weight | 215 lb (98 kg) |
Career information | |
High school | Oak Park (Kansas City, Missouri) |
College | Kansas (2018–2022) |
NBA draft | 2022 / Round: 1 / Pick: 14k overall |
Selected by the Cleveland Cavaliers | |
Pro playing career | 2022–present |
Career history | |
2022–present | Utah Jazz |
2022 | →Salt Lake City Stars |
Career highlights and awards | |
|
Ochai Young Agbaji (tí a bí ní April 20, 2000)[2] jẹ́ agbábọ́ọ̀lù alápẹ̀rè fún Utah Jazz èyí tó jẹ́ ti National Basketball Association (NBA). Gẹ́gẹ́ bí i ọ̀gá àgbà ní University of Kansas, wọ́n fún Agbaji lórúkọ, wọ́n sì dìbò fun ní ọdún 2022, gẹ́gẹ́ bí i Big 12 Player of the Year. Ó darí ẹgbẹ́ Jayhawks nínú ìdíje, títí wọ́n fi wọ ìpele tó kẹ́yìn, wọ́n sì sọ wọ́n ní Final Four Most Outstanding Player (MOP).
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Givony, Jonathan (June 24, 2022). "Ochai Agbaji Stats, News, Bio". ESPN. Retrieved June 24, 2022.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedtait_12112019