Jump to content

Ochiglegor Idagbo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ochiglegor Idagbo jẹ olóṣèlú ọmọ orilẹ-ede Nàìjíríà . O je ọmọ ẹgbẹ́ to n sójú àgbègbè Obudu/Bekwarra/Obanliku ni ilé ìgbìmọ̀ asofin . [1] [2]

Igbesi aye ibẹrẹ ati ẹkọ

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ochiglegor Idagbo ni won bi ni ọjọ 10 osu kọkànlá ọdún 1971 o si wa lati ipinle Cross River .

Ni 2015, o jẹ ọmọ ẹgbẹ ti o nsójú àgbègbè Obudu/Bekwarra/Obanliku. O tun yan ni ọdun 2019 fun ìgbà kejì, o si ṣiṣẹ bi alága ìgbìmò ile lori àkóónú agbegbe.

  1. https://citizensciencenigeria.org/public-offices/persons/ochiglegor-legor-idagbo
  2. https://constrack.ng/legislator_details?id=80