Oga Bolagi
Oga Bolaji | |
---|---|
Fáìlì:Oga Bolaji poster.jpg Film poster | |
Adarí | Kayode Kasum |
Olùgbékalẹ̀ | Mayowa Bakare |
Òǹkọ̀wé | Kayode Kasum Omo Ojeiwa |
Àwọn òṣèré | Ikponmwosa Gold Omowumi Dada Idowu Philips |
Ilé-iṣẹ́ fíìmù | Kaykas Studios |
Déètì àgbéjáde |
|
Àkókò | 90 minutes |
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Èdè | Afrikaans English Yoruba |
Oga Bolaji jẹ́ èré óńìṣè kan lati orile-ede Ńáìjírìá ńì ọ̀dùń 2018 tì ọ̀táń átì ólùdárì jẹ́ Kanọ̀dè Ka su mu. Èré yì ṣè áfìháń Ikponmwosa Gold, Omowumi Dada átì Idowu Philips gẹ́gẹ̀ bi olù ẹ́dá ítáń[1] Èré óńíṣè yí jádé ńí ọ̀jọ̀ kèjé oṣù kejè ọ̀dùń 2018 tì áwọ̀ń irísì àwọ̀ń èyáń ńìpá èré ńá ńìpè òdá. [2] Wọ̀ń ṣè áfìháń Ògá Bolaji ńì áwọ̀ń ọ̀dùń káń bì New York African Film Festival, Nollywood week Paris, Zimbabwe International Film Festival, RTF Film Festival, Cardiff Film Festival and Zanzibar International Festival.[3] Olùdárì èré yì ṣè áfìháń rẹ́ lọ̀fè lórì YouTube Ni ọ̀dùń 2020 fun Awọ̀ń eyan ti wọ̀ń wa ni ílé nigba átìmọ̀lè nipa ájákàlẹ̀ Coronavirus coronavirus pandemic in the country.[4][5]
Áfòyèmọ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oga Bolaji, jẹ́ ákórìń tì kò kọ́ órìń mọ̀ látì igbá tì ótì dì ómọ̀ ógòjì,bẹ́ńì ígbèsì aye re yi pada lati igba ti ó sa la pa de omọ̀ óbíńrìń kèkérè kan ti onẹ́ omọ̀dùń me je.[6]
Awọ̀ń óṣérè
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Ikponmwosa Gold gege bi Oga Bolaji
- Idowu Philips gẹ́gẹ̀ bì Mama Bolaji
- Omowumi Dada gẹ́gẹ̀ bì Victoria
- Gregory Ojefua gẹ́gẹ̀ bì Omo
- Jasmine Fakunle gẹ́gẹ̀ bì Ajua
- Ronke Ojo
- Officer Woos
Awọ̀ń itọ̀kásì
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Ẹda pamosi". www.nollywoodweek.com. Archived from the original on 2019-10-07. Retrieved 2020-05-03.
- ↑ "OGA BOLAJI". New York African Film Festival (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-05-13. Archived from the original on 2019-09-18. Retrieved 2020-05-03.
- ↑ Augoye, Jayne (2020-04-16). "Nigeria: Kayode Kasum Premieres 'Oga Bolaji' On YouTube". allAfrica.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-03.
- ↑ Augoye, Jayne (2020-04-15). "Kayode Kasum premieres ‘Oga Bolaji’ on YouTube" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-03.
- ↑ "Kayode Kasum's 'Oga Bolaji' premieres on YouTube". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-04-15. Retrieved 2020-05-03.
- ↑ "Oga Bolaji". Film at Lincoln Center (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-03.
External links
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Oga Bolagi , (IMDb) (Gẹ̀ẹ́sì)