Ogonna Chukwudi
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Ogonna Franca Chukwudi | ||
Ọjọ́ ìbí | 14 Oṣù Kẹ̀sán 1988 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Enugu, Nigeria | ||
Ìga | 1.61 m | ||
Playing position | Midfielder | ||
Club information | |||
Current club | S.S. Lazio Women 2015 | ||
Number | 17 | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
2005–2010 | Nassarawa Amazons | 23 | (23) |
2011–2013 | Umeå IK | 59 | (9) |
2014–2016 | KIF Örebro DFF | 56 | (14) |
2017–2018 | Kristianstads DFF | 42 | (7) |
2019 | Djurgårdens IF Fotboll (women) | 18 | (1) |
2020 | ZFK CSKA Moscow | 0 | (0) |
2021 | Madrid CFF | 2 | (0) |
2021- | S.S. Lazio Women 2015 | 3 | (0) |
National team | |||
2006– | Nigeria women's national football team | 20 | (3) |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 00:25, 1 February 2021 (UTC). † Appearances (Goals). |
Ogonna Chukwudi jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 14, óṣu September ni ọdun 1988. Arabinrin naa ṣere fun Italian club Lazio ati apapọ team awọn obinrin gẹgẹbi midfielder[1][2][3].
Àṣeyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ogonna kopa ninu FIFA Cup awọn obinrin agbaye ni ọdun 2011 nibi ti o ti ṣoju órilẹ ede naigiria[4].