Ojú
Appearance
Oju jẹ́ ẹ̀yà ara tí ẹranko àti ènìyàn ń lò láti ríran, ó fẹ́rẹ̀ jẹ́ gbogbo ẹranko ló ní ojú (ṣùgbọ́n àwọn ẹranko kan wà tí kò lójú) [1] Fún eniyan àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹranko, àwòrán tí ojú bárí á lọ sí ọpọlọ, ọpọlọ á sì túnmọ̀ àwòrán náà. Ènìyàn àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹranko ní ojú méji, àwọn ẹranko inú odò tí a tún ń pè ní "copepods" ní ojú kan [2], àwọn ẹranko mìíràn ní ojú mẹ́ta , àwọn mìíràn ní mẹ́rin. Ìjàm̀bá sí ojú le fa àìríran tàbí ìṣòro pẹ̀lú ìan rírí[3]
Ojú | |
---|---|
Schematic diagram of the vertebrate eye. | |
Compound eye of Antarctic krill |
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Mangan, Tom. "Animal Eyes". All About Vision. Retrieved 2022-03-06.
- ↑ "Introduction to copepods". Nobanis. Retrieved 2022-03-06.
- ↑ "what animal has 3 eyes". Lisbdnet.com. 2022-01-02. Archived from the original on 2022-02-23. Retrieved 2022-03-06.