Jump to content

Okey Igwe

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Okey Igwe jẹ́ olóṣèlú àti aṣofin ní orílè-èdè Nàìjíríà. O ti figba kan ṣoju àgbègbè Umunneochi ni ile ìgbìmò aṣofin ipinlẹ Abia. [1] [2] [3]