Oko Ẹru ti Adayeba
Oko Ẹru ti Adayeba (Tabi Oko Ẹru ti Aristotelian) jẹ ariyanjiyan lori Óṣèlu Aristotle to da loripe eniyan jẹ ẹru ni adayeba ṣugbọn awọn toku jẹ ẹru latari ofin tabi convention[1].
Ọrọ ti Aristotle sọ lóri oko ẹru
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Aristotle Ṣalaye pe ẹru adayeba jẹ ẹni ti o jẹ ọmọ gẹgẹbi adayeba ṣugbọn ẹlo mira lo ni. O ṣe alaye ṣiwaju pe ẹni naa ni oun alumọni ti olowo rẹ le lo nigba kigba to ba ti wu. Aristotle ṣe alaye pe kiko ni lẹru pẹlu agidi o kinṣe nkan to lere ninu nigba owo ẹru naa o ba tijẹ ti adayeba[2][3].
Iṣẹ Aristotle ni aimoye eniyan ti tako. Darrell Donns sọpẹ ọrọ Aristotle lori owo ẹru ko dọmọran to. Awọn olumoye yoku sọpẹ ipo ẹru adayeba ṣè yipada niwọn igba ti itumọ ti Aristotle fun adayeba ṣe yipada[4].
Ipà
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Stoic lodi ironu ti Aristotle lori owo ẹru ṣiṣe ti adayeba ni letter ti Seneca ati ibomiran[5]. Ni Century ti mẹrin dinlogun ti ilẹ amẹrica koni lẹru, ariyanjiyan lori kiko ni lẹru bẹrẹ. Ọpọlọpọ awọn akonilẹru lofi ọwọ si owo ẹru ṣiṣe ti wọn si lo aimoye ọna lati fi idi rẹ mulọ. Bartolomé de las Casas fi ọwọ si ṣiṣe awọn eniyan ni pẹlẹ pẹlẹ lori yiyi wọn pada lai ma kowọn lẹru. Las Casas lodi si ibaṣè awọn alawọ dudu lọwọ awọn Spaniards. Ni ọdun 1520, Las Casas ri Ọba Holy Roman Emperor Charles V (Charles I ti Spain) lori ṣise awọn eniyan ni jẹjẹ.
Ni óṣu April, ọdun 1550, Las Casas ati Juan Ginés de Sepúlveda pade ni ilu Spain lori ariyanjiyan nipa kiko awọn ilẹ America lẹru ati lori ọrọ Aristotle nipa ẹru ti adayẹba. Sepúlveda sọpa ipo aye tuntun awọn akonilẹru, awọn Amerindinas jẹ ẹru adayeba. Las Casas tako ọrọ Aristotle lori Barbarians ati lori lilo ọrọ naa fun awọn ilẹ Indian[6][7][8][9].
Itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Smith, Nicholas D. (1983). "Aristotle's Theory of Natural Slavery". Phoenix (Classical Association of Canada) 37 (2): 109–122. http://www.jstor.org/stable/1087451. Retrieved 2023-08-25.
- ↑ "Aristotle’s Defense of Slavery". 1000-Word Philosophy: An Introductory Anthology. 2019-09-11. Retrieved 2023-08-25.
- ↑ Heath, Malcolm (2008). "Aristotle on Natural Slavery". Phronesis (Brill) 53 (3).
- ↑ Dobbs, Darrell (1994). "Natural Right and the Problem of Aristotle's Defense of Slavery". The Journal of Politics (University of Chicago Press) 56 (1): 69–94.
- ↑ "The Stoic-Cynic". academic.oup.com. Retrieved 2023-08-25.
- ↑ "Bartolomé de Las Casas debates the subjugation of the Indians, 1550". AP US History Study Guide from The Gilder Lehrman Institute of American History. 2011-11-30. Retrieved 2023-08-25.
- ↑ "Juan Ginés de Sepúlveda". The Core Curriculum. Retrieved 2023-08-25.
- ↑ "New World Debate". AP European History. Retrieved 2023-08-25.
- ↑ Slack, Kevin (2018). "A Foucauldian Study of Spanish Colonialism". The Latin Americanist (Project MUSE) 62 (3).