Jump to content

Okoro Idozuka

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Okoro Idozuka jẹ oludari ti 19th Century ati jagun jagun ni agbegbe Arondizuogu, ilẹ Naijiria. Arakunrin naa jẹ olujiroro agba si oludasilẹ abule Ndiakunwanta Uno Arondizuogu. Okoro jẹ gbajumọ oniṣowo ẹru ṣiṣe to lowo lọwọ[1][2].

Idozuka ni a bisi agbegbe Awka ṣugbọn ti o ko lọsi Arondizuogu ni Century. Arakunrin naa pada yi órukọ Abisọ rẹ Bọda Okoli si ti Aro. Okoro jẹ baba fun Nwankwo Okoro[3][4]. Okoro Idozuka jẹ̀ ọkan lara awọn oludari to pataki ni Arondizuogu to si jẹ eniyan jakan ni Aro titi di eni[5].

Ìnira ti Okoro dojukọ

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ni ọdun 1819, awọn ẹniyan fi aimoye ẹsun kan Okoro lori jiji awọn eniyan gbe, eyi jẹ ọna lati ba owo arakunrin naa jẹ. Lati ra iyi rẹ̀ pada, Okoro mu lẹ, eyi jẹ ọkan lara imulẹ meje to tobi julọ ni aye igbana. Imulẹ yi ni eyi ti ẹni kẹni to ba fẹ mulẹ maa nṣe ti yo fi ori rẹ̀ bura fun awọn óriṣa ṣugbọn ti yoo lo ayọmọ awọn ẹni mẹfa to sumọ julọ. Imulẹ yii lagbara to bẹ gẹ to jẹ pe ti ẹni naa ba jẹbi ẹsun taa fikan, awọn óriṣa yii ko ni pa oun nikan afi ki wọn mu awọn mẹfa ti wọn fikun imulẹ naa. Fun ti imulẹ ti Mazi Okoli Idozuka fẹ ṣe, wọn ni ki o fi awọn molẹbi sinu imulẹ naa ati gbogbo awọn ọmọ ọkunrin ti a bisi ilẹ Akunwanta. Nigbati Mazi Okoro Idozuka ṣetan lati ṣè imulẹ naa, O wa awọn ọkunrin mẹfa ṣugbon o kuna a tiri ẹni keje ninu awọn ara ilẹ rẹ. Mmelonye yanda ọmọ rẹ Agosi, eyi lomu ki awọn to fi ẹsun kan Okoro jawọ kuro ninu ọrọ naa[6][7].

  1. "Okoro Idozuka". LiquiSearch. Retrieved 2023-08-25. 
  2. Accelerator, Academic (2023-08-25). "Aro Confederacy: Most Up-to-Date Encyclopedia, News & Reviews". Academic Accelerator. Archived from the original on 2023-08-25. Retrieved 2023-08-25. 
  3. "history of Arondizuogu". history of Arondizuogu - Wap.org.ng. 2023-05-29. Archived from the original on 2023-08-25. Retrieved 2023-08-25. 
  4. "History of Arondizuogu". Arondizuogu Progressive Front. Archived from the original on 2023-08-25. Retrieved 2023-08-25. 
  5. "Brief History Of Arondizuogu Of Arochukwu » Arochukwu Blog". Arochukwu Blog. 2022-09-13. Archived from the original on 2023-08-25. Retrieved 2023-08-25. 
  6. Asouzu, I. (2005). The Method and Principles of Complementary Reflection in and Beyond African Philosophy. Studies in African philosophy. Lit. p. 28. ISBN 978-3-8258-8578-6. https://books.google.com.ng/books?id=QFAYobukUN4C&pg=PA28. Retrieved 2023-08-25. 
  7. "Arondizuogu - History". LiquiSearch. Retrieved 2023-08-25.