Jump to content

Ola Brown

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Olamide Brown
Ọjọ́ìbíOlamide Orekunrin
1986 (ọmọ ọdún 37–38)
London, England
Iléẹ̀kọ́ gígaHull York Medical School, University of London
Iṣẹ́Oníṣòwò obìnrin
Olólùfẹ́David Brown

Olamide Brown (tí a bí ní ọdún 1986), jẹ́ oníṣègùn òyìnbó ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà mọ́ Ilẹ̀ọba Britain, oníṣòwò, ọ̀lùdásílẹ̀ Doctors Healthcare Investment Group àti adarí Greentree Investment Company.[1][2][3][4]

Flying Doctors Healthcare Group jẹ́ ilé-isẹ́ tí ó ń ṣètò gbígbé àwọn ènìyàn tí ó nílò ìtójú ìlera ara ní kíákíá lọ sí ilé ìwòsàn nípa ojú òfurufú, kíkó ilé ìwòsàn, títa àwọn irinsẹ́ ìṣègùn òyìnbó àti oògùn òyìnbó.[5][6][7]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Renni Edo-Lodge (September 12, 2014). "Nigeria's air ambulance firm is a leap forward for healthcare". United Kingdom. https://www.theguardian.com/global-development/2014/sep/12/nigeria-air-ambulance-firm-healthcare. 
  2. "DR. OLA OREKUNRIN Africa's high-flying doctor". Lionesses of Africa. 
  3. "Our Team". Greentree Investment Company. 
  4. "VC Firm, GreenTree holds Pitch Day for over 20 promising Startups". Nairametrics. 
  5. "African Doctor-Founder Develops Special COVID-19 Testing Booth That Don't Need Protective Gear". Weetracker. 
  6. "African Doctor-Founder Develops Special COVID-19 Testing Booth That Don't Need Protective Gear". Flying Doctors Nigeria. 
  7. "Flying Doctors launches Covid Mobile to ramp up testing, protect health workers". Business Day.