Ola Opesan
Ìrísí
Ola Opesan ni a bí ní ọdún 1966 jẹ́ onkòwé, oníròyìn àti olùkọ́ àti ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Brítènì . [1] Ó kọ ìwé rẹ̀ akọ́kọ́ tí ó jẹ́ ìwé ìtàn ọlọ́rọ̀ geere tí ó pe ní Another Lonely Londoner ní ọdún (1991), lábẹ́ ilé-iṣẹ́ òníẹ̀wé pseudonym.
Awọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Opesan's snapshots of Nigerian history, The Guardian, 19 January 2016. Accessed7 December 2020.