Olabiyi Yai
Ìrísí
Olabiyi Yai |
---|
Olabiyi Babalola Joseph Yaï (ọjọ́-ìbí 1939[1]) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Benin àti ọ̀jọ̀gbọ́n lítíréṣọ̀ ní ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ Èdè àti Lítíréṣọ̀ Áfíríkà ni Yunifásítí Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ (Obafemi Awolowo University) ní ìlú Ifẹ̀, ní orilẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ọdún 1988 ni olùkọ́ yìí fi ẹ̀yìn tì ní ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ yìí. Yai tún ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi aṣojú orílẹ̀-èdè Benin sí UNESCO, bẹ́ẹ̀ sì ni ó tún ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi alága ìgbìmọ̀ apàṣẹ rẹ̀.[2]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Olabiyi Babalola Joseph Yai - Biography". Archived from the original on 2009-09-09. Retrieved 2009-09-24.
- ↑ Election as Chairman to the Executive Board