Olasope O. Oyelaran

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Olasope O. Oyelaran je omo ile Naijiria ati ojogbon imo-eda-ede ni eka-eko Ede ati litireso Aafirika, ni Yunifasiti Obafemi Awolowo, Ile-Ife, Nigeria. Lati igba ti won ti da eka-eko yii sile ni 1975 o ti wa ni ibe. Ki o to di igba yii, o ti n sise ni Institute of African Studies, OAU, Ife, Nigeria lati 1970. Oun ni oluko akoko ni eka-eko Ede ati Litireso Aafirika, OAU, Ife, Nigeria. 1988 ni o feyinti ni eka-eko yii.