Olawale Sulaiman
Ìrísí
Professor Olawale Sulaiman, MD.,PhD., FRCS(C), CON jẹ́ oníṣẹ́abẹtọpọlọ tó gba ẹ̀kọ́ ní Canada àti America. Ó sì tún jẹ́ onímọ̀ àti oníṣegùn àgbà ní Nigerian heritage.[1][2] Òun sì ni olùdarí àgbà ní RNZ Global Ltd, èyí tí wọ́n ṣèdásílẹ̀ ní ọdún 2010.[3][4][5] Ní ọdún 2019, wọ́n yàn án sípò olùdámọ̀ràn fún gómíná Ìpínlẹ̀ Kwara, lórí ọ̀rọ̀ ìlera.[6][7][8][9][10][11][12]
Awọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Aisha Salaudeen (3 October 2019). "Nigerian neurosurgeon takes pay cut to perform free operations". CNN. Retrieved 2019-10-04.
- ↑ "Nigerian performs first MIS spine surgery in Sub-Saharan Africa". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 7 May 2017. Retrieved 2019-10-04.
- ↑ "World-class doctor operates Fregene in major surgeries". The Nation Newspaper (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-09-06. Retrieved 2019-10-04.
- ↑ Kenney, Tanasia (2018-03-08). "Black Surgeon Saves Lives in New Orleans And Nigeria, Often for Free". Atlanta Black Star (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-10-04.
- ↑ Olaoye, Wole (2019-07-28). "Milk of African kindness". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-07-29. Retrieved 2019-10-04.
- ↑ Njoku, Ime (2019-08-26). "Dr Wale Sulaiman appointed Special Adviser on Health Matters in Kwara". Voice of Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-10-04.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "Kwara govt offers free surgery to 500 patients". TVC News Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 29 September 2019. Retrieved 2019-10-04.
- ↑ Oni, Stephen Olufemi; Ilorin (2019-09-22). "500 for Kwara surgical interventions". Newtelegraph (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-10-30. Retrieved 2019-10-04.
- ↑ Online, Tribune (2019-09-23). "500 residents benefit medical, surgical intervention in Kwara". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-10-04.
- ↑ Online, Tribune (2019-08-26). "Kwara to overhaul health system, say AbdulRazaq , senators". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-10-04.
- ↑ "Kwara gov appoints US-based neurosurgeon as health aide". The Sun Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-08-28. Retrieved 2019-10-04.
- ↑ Oni, Stephen Olufemi (2019-09-29). "35% rise in public hospital patronage as Kwara prioritises healthcare". Newtelegraph (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-09-29. Retrieved 2019-10-04.