Jump to content

Old town of Ghadames

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àwòrán Old town of Ghadames

Àdàkọ:Unreferenced

Old town of Ghadames
Agbègbè Àjọgúnbá Àgbáyé ti UNESCO
View over the rooftops of the old town of Ghadames
Ibi tí ó wàGhadames, Libya
ÌlànàÀdàkọ:UNESCO WHS type
Ìtọ́kasí362
Ìkọsílẹ̀Àdàkọ:If first display both
Ìtóbi rẹ̀38.4 ha (95 acres)
Àwọn ipò55°07′30″N 09°29′49″E / 55.12500°N 9.49694°E / 55.12500; 9.49694Coordinates: 55°07′30″N 09°29′49″E / 55.12500°N 9.49694°E / 55.12500; 9.49694

Old town of Ghadames (Lárúbáwá: مدينة غدامس القديمة‎) ni ó jẹ́ ìlú atìjọ́ kan tí wọ́n ń pè ní Ghadames, tí ó wà ní orílẹ̀-èdè Libya tí ó sì jẹ́ ìkan nínú ìlú tí ó wà ní ilẹ̀ aṣálẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Libya tí wọ́n ń pè ní "Jewel of the Desert" wọ́n fi ìlú náà sí abẹ́ UNESCO world heritage ní ọdún 1986.

Ètò ìkọ́lé wọn

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ìlú Ghadames ni ó pín sí ìletò méje tí wọ́n já pọ̀ mọ́ra wọn láti di ìlú ńlá kan. Àwọn ilé tí eọ́n kọ́ náà ni ó bá ìlànà ìkọ́lé ní àwọn ilé aṣálẹ̀ mu látàrí bí ][om]] ṣe wọ́n níbẹ̀. Bí wọ́n ṣe kọ́lé gbe ara wọn wọ̀nyí ni ó mú kí ooru gbígbóná ibẹ̀ ó dínkù.Àdàkọ:Cn

Page Module:Portal/styles.css has no content.