Jump to content

Oleta Adams

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Oleta Adams
Background information
Orúkọ àbísọOleta Angela Adams
Ọjọ́ìbí4 Oṣù Kàrún 1953 (1953-05-04) (ọmọ ọdún 71)
Seattle, Washington, U.S.
Irú orinGospel, soul[1]
Occupation(s)Singer
InstrumentsVocals, piano
Years active1980–present
Labels
Associated actsTears for Fears, Mervyn Warren, Brooklyn Tabernacle Choir
Websiteoletaadams.com


Oleta Adams (ojoibi May 4, 1953) jẹ̀ akọrin ẹ̀mí àti àti atẹdùùrù ará Amẹ́ríkà tó gbajúmọ̀ fún agbára ohùn rẹ̀.

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayẹ́ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Adams tí wón bí gẹ́gẹ́ bí ọmọbìnrin si ajíhìnrere, ti o si dàgbà sí gbígbọ́ orin ẹ̀mí. Nígbà tí o dàgbà, awọn ẹbí rẹ̀ kólọ sí Yakima, Washington. Ó bẹ̀rē orin kíkọ ni sọ́ọ́sì.

Kí ó tó rí ànfàní láti kọ orin rẹ, Adams fojú winá ọ̀pọ̀lọpọ̀ kíkọ̀sílẹ̀. Ni ọdún 1970s, ó ko lọ si Los Angeles, California, níbi tí o ti o se rẹ́kọ́dù.

Pẹ̀lú àmọ̀ràn olùkọ́ rẹ, Lee Farrell, o kó lọ si Kansas City, Missouri, níbi tí o tí se awọn oríṣiríṣi kikọ orin ni ibi ipejopo.

Ní ọdún 1994, Adams fẹ́ ònílù tí orúko rè njé John Cushon ni Methodist church ti o wa ni Kansas. Wọ́n pàdé ní ọdún 1980 nígbà tí wón jo n se rẹ́kọ́dù fun Adams.[2]

Awards and nominations

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Year Result Award Category Work
1991 Nominated Soul Train Music Award Best R&B/Urban Contemporary New Artist
1992 Nominated Grammy Awards Best Female Pop Vocal Performance
"Get Here"
1993 Nominated Grammy Awards Best Female R&B Vocal Performance
"Don't Let The Sun Go Down On Me"
1994 Nominated Soul Train Music Award[3] Best R&B Single, Female
"I Just Had to Hear Your Voice"
1997 Nominated Grammy Awards Best R&B Album
Moving On
1998 Nominated Grammy Awards Best Contemporary Soul Gospel Album
Come Walk with Me
  1. Cooper, William. "Oleta Adams". AllMusic. Retrieved March 12, 2018. 
  2. Norment, Lynn (1996). "Moving on and up with Oleta Adams: with new husband and renewed religious faith, soulful singer scores with new album". Ebony. http://findarticles.com/p/articles/mi_m1077/is_n10_v51/ai_18544356. 
  3. "Jet". Johnson Publishing Company. 14 March 1994 – via Google Books.