Jump to content

Oliver Muoto

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Oliver Muoto jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Naijiria tí ó ń gbé ní ìlú Poland. Bàbá rẹ̀ jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Naijiria, ìyá rẹ̀ sì jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Poland. Oliver jẹ́ olókòwò ilẹ̀ Poland.


Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]