Olivia Amoako

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Olivia Amoako
Personal information
Ọjọ́ ìbí30 Oṣù Kẹ̀sán 1985 (1985-09-30) (ọmọ ọdún 38)
Playing positionDefender
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
Ghatel Ladies
National team
Ghana women's national football team3(0)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.

† Appearances (Goals).

‡ National team caps and goals correct as of 18 March 2017


Olivia Amoako jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 30, óṣu september ni ọdun 1985. Agbabọọlu naa ṣere fun awọn ọdọmọbinrin Ghatel gẹgẹ̀bi defender[1][2][3][4].

Àṣeyọri[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Olivia kopa ninu FIFA Cup awọn obinrin agbaye to waye ni ọdun 2007[5][6].

Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. https://fbref.com/en/players/aa9a943f/Olivia-Amoako
  2. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2022-06-25. Retrieved 2022-06-25. 
  3. https://www.worldfootball.net/player_summary/olivia-amoako/
  4. https://www.fifa.com/tournaments/womens/womensworldcup/china2007/teams/1883721
  5. https://m.goalzz.com/?player=35156
  6. https://ng.soccerway.com/players/olivia-amoako/19578/