Olivier Niyungeko
Ìrísí
Alain Olivier Niyungeko (ti a bi ni ọjọ kewa Oṣu Kẹwa Ọdun 1970) jẹ olukọni bọọlu lati orilẹ-ede Burundi, ẹniti o jẹ oluṣakoso kẹhin ti Burundi .
Lakoko akoko 2012–13, Niyungeko dari egbe agbabọọlu Flambeau de l'Est si akọle Premier League Burundi akọkọ wọn, ọdun mẹta lẹhin idasile.
Ni ọdun 2016, Niyungeko ni wọn yan Gẹgẹ bi oluṣakoso Burundi, ti o rọpo Ahcene Aït-Abdelmalek .