Olori

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Olori tí atún mò sí Aya Ọba tàbí iyawo oba jé iyawo sí oba tówà ní orí oyè. Ní àwon ìlú tàbí agbegbe tí asa wón gbà ki oba fé ju iyawo kan lo, a le pe gbogbo ìyàwó oba ní ayaba. Bí o tile jé wípéwipe ayaba jé eni iyi ní awujo, ko ní agbara kankan lowo ararè ní òpòlopò àsà, bi ní orílè-èdè United Kingdom(Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan) ati ní Ile Yorùbá. [1]

Àwon Ìtókasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Westbrook, Caroline (2022-02-06). "What is a Queen Consort?". Metro. Retrieved 2022-03-21.