Jump to content

Oluwakemi Adejoro Ojo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Oluwakemi Adejoro Ojo
Orúkọ mírànKemi Korede
Ọmọ orílẹ̀-èdè Nigeria
Iṣẹ́Film actress, TV presenter, Producer
Ìgbà iṣẹ́2006- till present
Àwọn ọmọ3

Oluwakemi Adejoro Ojo Yo-Oluwakemi Adejoro Ojo.ogg Listen, tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí Kemi Korede, jẹ́ òṣèrébìnrin, àti olóòtú ètò orí tẹlifíṣọ́ọ̀nù, bẹ́ẹ̀ sì ni ó jẹ́ aṣagbátẹrù ayẹyẹ. Wọ́n máa ń ṣàfihàn rẹ̀ nínú àwọn fíìmù Yorùbá.[1][2][3][4] Oluwakemi àti Toyin Alausa ni wọ́n jọ tẹwọ́bọ̀wé fún Honeyglow skin care ní ọdún 2021, ẹni tó ni ilé-iṣé náà ló ṣètò èyí.[5]

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Fún ẹ̀kọ́ ilé-ìwé gíga, ó kẹ́kọ̀ọ́ nípa iṣé nọ́ọ̀sì.[6]

Iṣẹ́ tó yàn láàyò

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Kemi Korede bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré-ṣíṣe láti ìgbà tó wà ní ilé-ìwé girama, àmọ́ ó bọ́ sí gbàgede ní ọdún 2006, tó sì kópa nínú fíìmù Omobewaji[7]

Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • Ile Olorogun
  • Afi ibi Solore
  • Obo Iyi
  • Satan’s Bride
  • Oju Ade
  • Omo Aye
  • Omobewaji[8]
  • Ignorance
  • Wemimo
  • Ojoor
  • Khafila[9]
  • Current Alhaja
  • Abo Oja

Ìgbésí ayé rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Kemi ti lọ́kọ, ó sì ti bímọ mẹ́ta.[10]

  1. "Adunni Ade: People make me nervous". The Nation Newspaper (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-05-07. Retrieved 2022-08-02. 
  2. "Kemi Korede To Funke Akindele: You're A Woman of substance". Independent Newspaper Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-02-16. Retrieved 2022-08-02. 
  3. "You're a rare gem, actress Kemi Korede praises Funke Akindele". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-02-16. Retrieved 2022-08-02. 
  4. "Why I sometimes feel like quitting acting — Ife Olawale". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-02-23. Retrieved 2022-08-02. 
  5. Online, Tribune (2021-08-02). "Toyin Alausa, Jide Awobona, Kemi Korede, others join Honeyglow family". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-02. 
  6. Kehinde, Seye (2018-10-01). "Why I Left My Nursing Career For Acting – Pretty Actress, KEMI KOREDE Tells City People". City People Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-02. 
  7. Online, Tribune (2019-02-09). "With N500m, you can tame me —Actress, Nkechi Blessing Sunday". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-02. 
  8. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :12
  9. Kaduna, George (2021-12-12). "INTERVIEW: Instagram critics strengthening my relationship with my husband - Blessing Nkechi". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-02. 
  10. Online, Tribune (2020-07-26). "Femi Adebayo, Fathia, others honour Kemi Korede". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-02.