Oluwaseun Osowobi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Oluwaseun Ayodeji Osowobi
Ọjọ́ìbíLagos
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ẹ̀kọ́Ahmadu Bello University
OrganizationStand to End Rape

Oluwaseun Ayodeji Osowobi je ajafeto omo obirin ni Naijiria. Ohun ni Oludasile ati alakoso Stand to End Rape (STER) Initiative. Ni odun 2019 ohun ni Obirin Naijiria elekeji ti won fi ami idanimo akojo Time 100 Next dalola, be si ti nu pe otun gba ami eye ti Commonwealth Young Person of the Year fun odun 2019..

Igbe Aye[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Osowobi je omobibi ile Naijiria, ikose ati igboya iya ti obi lomo, loje ki odi aja fun eto omo eniyan.[1] O je omo akeko gboye local government and development studies ni ile iwe giga ti Ahmadu Bello University[1] ki o to lo si Swansea University fun imo eko Master’s degree lori International Relations. Iwe ase jade e, da lori iwon tun wonsi larin omo kunrin ati obirin pelu igbo kotun ti iwa afi pa bani lopo larin Omobirin ati Omode.[2]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 "Oluwaseun Ayodeji Osowobi". womendeliver.org. Retrieved December 27, 2020. 
  2. Donovan, Ben (March 28, 2018). "Swansea student wins prestigious Commonwealth Young Person of the Year award". 2018.swansea.ac.uk. Retrieved December 27, 2020.