Jump to content

Omar Berdouni

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Omar Berdouni
Ọjọ́ìbí20 Oṣù Keje 1979 (1979-07-20) (ọmọ ọdún 45)
Tangier, Morocco
Orílẹ̀-èdèMoroccan
Ọmọ orílẹ̀-èdèMorocco
Iṣẹ́Actor
Notable workUnited 93

Omar Berdouni (tí a bí ní ọjọ́ ogún oṣù keje ọdun 1979) jẹ́ òṣeré ọmọ orílẹ̀ ède Morocco

Ó ti kópa nínú òpò eré, díẹ̀ nínú wọn ni The Hamburg Cell, United 93, "The Situation", The Kingdom àti Extraordinary Rendition, directed by Jim Threapleton.[1] Ó tún kópa gẹ́gẹ́ bi Leonardo DiCaprio nínú eré Body of Lies.

Ní ọdún 2009, ó kó ipa gẹ́gẹ́ bi Ahmed nínú eré BBC kan tí àkọlé rẹ̀ jẹ́ Occupation. Ó tún kó ipa nínú eré Les Chevaliers du Ciel ní ọdún 2005 àti nínú eré Green Zone ní ọdún 2010.

Àwọn eré tí ó ti farahàn

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Year Title Role Notes
2000 Kasbah Driss
2003 Pompeii: The Last Day Callistus TV movie
2003 Ancient Egyptians Thutmosis Episode: "The Battle of Megiddo"
2004 The Predator Predator Short
2004 The Hamburg Cell Ramzi bin al-Shibh TV movie
2005 Sky Fighters Aziz Al Zawhari
2005 Andalus Zine
2006 United 93 Ahmed al-Haznawi
2006 The Situation Bashar
2007 Sparkle Luis
2007 Extraordinary Rendition Zaafir
2007 The Kingdom Prince Ahmed Bin Khaled
2008 Body of Lies Al-Saleem's Lieutenant
2009 Occupation Ahmed 2 episodes
2010 Green Zone Righteous Ali
2013 Captain Phillips Nemo
2018 Entebbe Faiz Jaber

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Presentation of Extraordinary Rendition on Eurochannel website