Omo-Love Branch
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 10 Oṣù Kínní 1974 | ||
Playing position | Defender | ||
National team‡ | |||
Nigeria | |||
† Appearances (Goals). ‡ National team caps and goals correct as of 5 June 1995 (before the 1995 FIFA Women's World Cup) |
Omo-Love Branch (tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹwàá, oṣù kìíní ọdún 1974) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá bìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí ó máa ń gbá bọ́ọ̀lù ní àyè àbò-ilé fún ọkọ̀ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin Nigeria. Ó wà lára ikọ̀ àkọ́kọ́ àwọn obìnrin tí wọ́n ṣojú Nàìjíríà nínú ìdíje 1991 FIFA Women's World Cup àti 1995 FIFA Women's World Cup.[1]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "FIFA Women's World Cup Sweden 1995 - Teams". FIFA Women's World Cup Sweden 1995. FIFA. 1995. Archived from the original on 2 July 2015. Retrieved 2007-09-28. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)