Omolola Itayemi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Omololá Ìtáyemí jẹ́ akọ̀ròyìn, àti àrẹ National Association of Travel and Tourism Writers of Nigeria (ATTWON), arìnrìn àjò àti ìgbafẹ́ ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[1][2]

Àwọn ìtọ́ka sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "NTDC, others reject proposed tourism bill – The Sun Nigeria". The Sun Nigeria. 2017-06-14. Retrieved 2018-10-13. 
  2. "ATTWON Debuts with Tourism Statistics Debate". THISDAYLIVE. 2017-12-09. Retrieved 2018-10-13.