Omotayo Akinremi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Omotayo Akinremi
Òrọ̀ ẹni
Orúkọ àbísọOmotayo Akinremi
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ọjọ́ìbí13 Oṣù Kẹ̀sán 1974 (1974-09-13) (ọmọ ọdún 49)
Iṣẹ́sprinter and hurdler
Sport
Orílẹ̀-èdèNigeria

Omotayo Akinremi (tí wọ́n bí ní 13 September 1974) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-edè Nàìjíríà tó máa ń kópa nínú ìdíje eré-sísá. Ó kópa nínú ìdíje àárín orílẹ̀-èdè àti ní àgbáyé, tó ṣojú Nàìjíríà. Ó gbé ipò kìíní, tó sì mu gba àmì-ẹ̀yẹ wúrà nínú ìdíje1992 àti 1993 African Championships in Athletics ní eré sísá onírinwó mítà. Bákan náà ni ó gba àmì-ẹ̀yẹ onídẹ ní ìdíje ti ọdún 1990 àti ní àsìkò 1991 All-Africa Games, níbi tí ó ti gba àmì-ẹ̀yẹ onídẹ nínú ìdíje irinwó mítà. Síwájú si, ó kópa nínú ìdíje ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà fún 4 × 400 m relay team, tó sì gba àmì-ẹ̀yẹ onídẹ nínú ìdíje 1993 Summer Universiade pẹ̀lú Olabisi Afolabi, Omolade Akinremi àti Onyinye Chikezie.[1][2]

Àwọn àṣeyọrí rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ìdíje ti àgbáyé[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Aṣojú fún Nàìjíríà Nàìjíríà
1990 World Junior Championships Plovdiv, Bulgaria 3rd 4 × 400 m relay 3:33.56

Àwọn ìdíje ti ilẹ̀ Africa[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Aṣojú fún Nàìjíríà Nàìjíríà
1990 African Championships Cairo, Egypt 3rd 400 metres hurdles 57.43
Aṣojú fún Nàìjíríà Nàìjíríà
1992 African Championships Belle Vue Maurel, Mauritius 1st 400 m 52.53
Aṣojú fún Nàìjíríà Nàìjíríà
1993 African Championships Durban, South Africa 1st 400 m hurdles 57.59

African Games[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Aṣojú fún Nàìjíríà Nàìjíríà
1991 All-Africa Games Cairo, Egypt 3rd 400 m hurdles 58:85

Summer Universiade[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Aṣojú fún Nàìjíríà Nàìjíríà
1993 Universiade Buffalo, United States 7th 400 m hurdles 58.47

Ìkópa rẹ̀ tó dára jù[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • 400 metres hurdles – 57.59 s (1992)
  • 400 metres – 52.53 s (1993)

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "1993 Universiade Summer". Universiade. 3 January 2014. Retrieved 9 July 2014. 
  2. "Omotayo Akinremi". IAAF World Athletics. 3 January 2014. Retrieved 9 July 2014.