Omotayo Oduntan
Lateefat Okunnu | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Lateefat Okunnu 3 Oṣù Kejìlá 1939 |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ | Civil servant |
Gbajúmọ̀ fún | Gómìnà ìpínlè Èkó |
Omotayo Aramide Oduntan (tí a bí ní ọjọ́ Kàrún oṣù kẹfà ọdún 1957), jé olósèlú ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó ń se asojú ekun Alimosho II ní house Assembly ìpinlè Èkó, o jé omo egbé oselu All Progressive Congress(APC).[1]
Ayé rè àti isé rè
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]A bi Omotayo Oduntan ní Ìpinlè Èkó, orílè-èdè Nàìjíríà, nibi tí o ti pari ìwé primari àti Sekodiri rè. O gba àmì-èye ninú ìmò food hygiene àti food handling ní ilé-ìwé Royal Institute of public Health. O lo sáà gégé bí asjou Alimosho II ni house assembly ti ìpínlè Èkó.
Ìdílé rè
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Omotayo ní igbeyawo rè àkókó(pèlú Ojogbon Ore Yusuf) tuka léyìn odun merin, o sì ni oun lo sokunfa idi tí igbeyawo náà fi tuka. Bí o tile jé wipe o se igbeyawo ní omokekere(nigba tí o je omo odun mokandinlogun), igbeyawo won ni omo meta laarin odun merin., èyí ti ìkan ninú won padà fi ayé sílè. O pada fé Reverend Bola Oyeledun. eni tí o jé ojise Olorun.[2]
Àwon ìtókasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Omotayo Oduntan". DBpedia. 1957-06-05. Retrieved 2022-05-30.
- ↑ "'My life at 60' – Hon. Omotayo Oduntan Oyeledun". Encomium Magazine. 2017-06-05. Retrieved 2022-05-30.