Jump to content

Omowunmi Sadik

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Omowunmi Sadik
Ìbí1964
Lagos, Nigeria
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian
PápáSurface chemistry, Environmental nanotechnology
Ilé-ẹ̀kọ́Binghamton University
Ibi ẹ̀kọ́University of Lagos, Wollongong University
Notable studentsSamira Musah

Omowunmi "Wunmi" A. Sadik (tí a bí ní ọjọ́ 19 oṣù kẹfà, ọdún 1964) jẹ́ ọ̀jọ́gbọ́n orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, onímọ̀ nípa oògún, àti aṣèdásílẹ̀ ohun ọ̀tun tó ń ṣịṣẹ́ ní Binghamton University. Ó ti ṣàgbékalẹ̀ microelectrode biosensors fún ṣíṣàwárí oògùn àti èròjà bọ́m̀bù. Ó sì ń ṣiṣẹ́ lórí ìdàgbàsókè àwọn ẹ̀rọ amáyẹrọrùn fún ìlòtúnlò èròjà irin láti inú ìdọ̀tí, fún lílò láwùjọ.[1] Ní ọdún 2012, Sadik ṣàjọdá ẹgbẹ́ non-profit Sustainable Nanotechnology Organization.[2]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Woman.NG (2018-07-07). "How Omowunmi Sadik Keeps Breaking New Grounds In Scientific Research". Woman.NG (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-09-10. Retrieved 2020-05-26. 
  2. "Sadik bio". sites.nationalacademies.org. Retrieved 2020-05-26.