Jump to content

Omu sise

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Kittens nursing
Lactating female coyote with visible teats

Omú Sísẹ̀ ṣe àpèjúwe ìtújáde wàrà láti àpò wàrà tí wọ́n ń pè ní Mammary Gland, àti ìgbà tí ìyá ọmọ bá ń fún ìyá ní wàrà mu ní èyí jẹ́. Ìlànà náà máa wáyé ní ọnà àrà ní ará ẹni tí ó bá jẹ́ obìnrin tàbí abo tí ó ti bàlágà.[1] ìlànà tí àwọn abo máa ń gbà fún àwọn ọmọ ní wàrà ní a ń pẹ̀ ni Ìtọ́mọ, bákan náà ni àwọn tí ó bá ń tọjú ni à ń pẹ̀ ní "Ìfọ́mọlọ́mú". Àwọn ọmọ ìkókó tí a ṣẹ̀sẹ̀ bí gan á máa mu wàrà láti inú ará wọn, èyí tí a lè pè ní colloquially tàbí "witch's milk"

Ní ará àwọn ẹdá mìíràn tí ó wà, Ọmú ṣíṣẹ̀ jẹ́ àmì pé Ọmọ obìrin tàbí àbò tí ní oyún rí ni ìgbà kàn láyé rẹ, amò ní ara ẹ̀yà àwọn èèyàn àti àwọn ewúrẹ, èyí lẹ̀. Wáyé láì sí oyún rárá.[2][3] A lé sọ pé Gbogbo ọ̀sìn ni ó ní Orí Ọmú; yàtọ̀ sí àwọn ọ̀sìn tí wọ́n ń pẹ̀ ní "Monotremes", àwọn ọ̀sìn tí wọ́n máa ń yé ẹyin, èyí tí ó jẹ́ pé dípò ṣíṣẹ̀ wàrà láti ọmù, wàrà a máa jáde nínú ikú nípasẹ̀ ducts. Ọ̀sìn kan tí ó máa ṣé èyí tí ó sí jẹ́ Akọ ní Dayak Fruit bat tí ó jẹ́ Àdán tí a lè rí ní Apa gúúsù oòrùn Asia.

''Galactopoiesis'' jẹ́ ìtọ́jú ìselọ́pọ̀ wàrà. Ìpele yìí nílò Prolactin. Oxytocin jẹ́ ohun tí ó ṣe pàtàkì fún ṣíṣẹ̀ wàrà fún mímú àwọn ìkókó. [[Galactorrhea]] jẹ́ ìṣelọ́pọ̀ wàrà kò ní nǹkan ṣe pẹ̀lú ìtọ́mọ. Nítorí èyí lè wáyé láàrin àwọn ọ̀sìn yálà abo tàbí akọ èyí jẹ́ bẹ́ẹ̀ nítorí àwọn àìsedédé Hòmónì (hormones) tí Wọ́n, ń pè ní ​[[hyperprolactinaemia]].

[[File:Zanzibar 31.JPG|thumb|240px|Breastfeeding of an older child]]

Láàrin àwọn èèyàn

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Milk secretion from a human breast

Àwọn ipá Hòmónù

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Látí ọ̀sẹ̀ Kejìdínlógún tí à bá tí ní Oyún, láàárín ipele Kejì àti kẹta oyún níní, ará Obìnrin yóò máa sún àwọn Hòmónù kàn èyí tí ó máa ń jékí ìdàgbàsókè wà ní ibì tí wàrà tí ń sẹ̀ nínú õmú igbáyà obìnrin.

Èyí tún jẹ̀ ohun tí ó sẹsẹ́sẹ́ ní ọmú ṣíṣẹ̀ láìsí oyún, tàbí nigba tí oyun bá wà nipasẹ̀ lílọ àwọn oògùn lórísirísi bí Birth Control pills, galactagogue, àti fífa wàrà jáde pẹ́lù .breast pump.

Breastfeeding (Correct Latch-On Position)
Breastfeeding a newborn baby
Breastfeeding of an older child
  1. Capuco, A. V.; Akers, R. M. (2009). "The origin and evolution of lactation". Journal of Biology 8 (4): 37. doi:10.1186/jbiol139. PMC 2688910. PMID 19439024. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=2688910. 
  2. "Lactating Without Pregnancy". sites.google.com. Archived from the original on 2021-01-14. Retrieved 2023-08-05. Àdàkọ:Rs
  3. "Goats with Precocious Udder Syndrome". Archived from the original on January 14, 2021. 
  4. 4.0 4.1 Mohrbacher, Nancy; Stock, Julie (2003). The Breastfeeding Answer Book (3rd ed. (revised) ed.). La Leche League International. ISBN 978-0-912500-92-8.