Wàrà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
A glass of pasteurized cow's milk
Cows being milked

Wàrà ni ohun mímu funfun olómi tí ó ní èròjà aṣara lóore tí a ma ńnfún láti ẹnu ọmú Màlúù, tí ó sì jẹ́ ìpìlẹ̀ èròjà ìdàgbà-sókè fún ọmọ màlúù tí ó bá ń mumú àti ọmọ ènìyàn pàá pàá, kí wọ́n tó bẹ̀rẹ̀ sí jẹun.[1] Nínú wàrà ni Kolósítírọ́ọ̀mù tí ó jẹ́ èròjà aṣara-lóore gan an sodo sí nígbà tí èyíkéyí ẹranko alégun lẹ́yìn afọ́mọ lọ́mú bá kọ́kọ́ fọ́mọ rẹ̀ lọ́mú. Kolósítírọ́ọ̀mù yí ni ó kún fún èròjà ọmọ ogun ara tí ó ń jáde láti ara ìyá sí ara ọmọ rẹ̀ tó ń mumú láti dáàbò bòó kúrò lọ́wọ́ àrùn àti àìsàn àìfojúrí, ó tún kún fún àwọn èròjà mìíràn tó ń ṣara-lóore.[2] Lára àwọn èròjà tí kolósítírọ́ọ̀mù kó sínú ni : èròjà amára-jọ̀lọ̀ (protein) àti èròjà afára-lókun (lactose). [3][4] [5][6]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Van Winckel, M; Velde, SV; De Bruyne, R; Van Biervliet, S (2011). "Clinical Practice". European Journal of Pediatrics 170 (12): 1489–1494. doi:10.1007/s00431-011-1547-x. PMID 21912895. 
  2. Pehrsson, P.R.; Haytowitz, D.B.; Holden, J.M.; Perry, C.R.; Beckler, D.G. (2000). "USDA's National Food and Nutrient Analysis Program: Food Sampling". Journal of Food Composition and Analysis 13 (4): 379–89. doi:10.1006/jfca.1999.0867. Archived from the original on April 7, 2003. https://web.archive.org/web/20030407085442/http://www.nal.usda.gov/fnic/foodcomp/Data/Other/jfca13_379-389.pdf. 
  3. Van Esterik, Penny (1995). "The Politics of Breastfeeding". In Stuart-Macadam, Patricia; Dettwyler, Katherine Ann. Breastfeeding: Biocultural Perspectives. Aldine. ISBN 978-0-202-01192-9. 
  4. Radbill, Samuel X. (1976). "The Role of Animals in Infant Feeding". In Hand, Wayland D. American Folk Medicine: A Symposium. University of California Press. ISBN 978-0-520-04093-9. 
  5. Gagnon-Joseph, Nathalie (February 17, 2016). "Three approaches to the milk glut". The Chronicle (Barton, Vermont): pp. 1A, 24A, 25A. https://bartonchronicle.com/three-approaches-to-the-milk-glut/. Retrieved March 1, 2016. 
  6. Hemme, T.; Otte, J., eds (2010). Status and Prospects for Smallholder Milk Production: A Global Perspective. Food and Agriculture Organization of the United Nations. http://www.fao.org/docrep/012/i1522e/i1522e00.pdf. Retrieved December 1, 2011.