Jump to content

Màlúù

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Cattle)

Màlúù
Cattle
A Swiss Braunvieh cow wearing a cowbell
Ipò ìdasí
Ọ̀sìn
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ edit ]
Ìjọba: Animalia (Àwọn ẹranko)
Ará: Chordata
Ẹgbẹ́: Mammalia (Àwọn afọmúbọ́mọ)
Ìtò: Oníka-dídọ́gba
Ìdílé: Bovidae
Subfamily: Bovinae
Ìbátan: Bos
Irú:
B. b. taurus
Ìfúnlórúkọ méjì
Bos bos taurus
Subspecies
Bovine range
Synonyms
  • Bos primigenius
  • Bos indicus
  • Bos longifrons

Màlúù takọ tabo ni wọ́n wọ́pọ̀ láàrin àwọn ẹranko ọ̀sìn ilé. Wọ́n jẹ́ ọ̀kan lára ìsọ̀rí ẹbí àwọn ẹranko tí a mọ̀ sí Bovinae, tí wọ́n wọ́pọ̀ ju màlúù kẹ̀tẹ̀ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.

Wọ́n sábà ma ń rè tàbí sin màlúù gẹ́gẹ́ bí ohun ọ̀sìn fún jíjẹ, pípèsè ẹran, fífi awọ rẹ̀ ṣe pànmọ́, ohun tí a lè fi pèsè wàrà, wọ́n ń lò wọ́n fún kíkọ ebè oko, lílo ìgbẹ́ rẹ̀ fún ajílẹ̀, tí ọ̀pọ̀ níní àwọn ẹ̀yà kan ní ilẹ̀ India ma ń sìn ín gẹ́gẹ́ bí òrìṣà tabí ọlọ́run wọn. [1] According to an estimate from 2011, there are 1.4 billion cattle in the world.[2].[3]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]