Ẹranko afọmúbọ́mọ
Appearance
Àwọn ẹranko afọmúbọ́mọ ni àwọn ẹranko elégungun tí wọ́n wà nínú ìtòsílẹ̀ ẹgbẹ́ Mammalia ( /məˈmeɪliə/), wọ́n ṣe é dámọ̀ pẹ̀lú ọyàn tí àwọn abo wọn ní láti ṣe mílíkì fún ọmọ-ọwọ́ wọn.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |