Màlúù
Appearance
Màlúù Cattle | |
---|---|
A Swiss Braunvieh cow wearing a cowbell | |
Ipò ìdasí | |
Ọ̀sìn
| |
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ edit ] | |
Ìjọba: | Animalia (Àwọn ẹranko) |
Ará: | Chordata |
Ẹgbẹ́: | Mammalia (Àwọn afọmúbọ́mọ) |
Ìtò: | Oníka-dídọ́gba |
Ìdílé: | Bovidae |
Subfamily: | Bovinae |
Ìbátan: | Bos |
Irú: | B. b. taurus
|
Ìfúnlórúkọ méjì | |
Bos bos taurus | |
Subspecies | |
Bovine range | |
Synonyms | |
|
Màlúù takọ tabo ni wọ́n wọ́pọ̀ láàrin àwọn ẹranko ọ̀sìn ilé. Wọ́n jẹ́ ọ̀kan lára ìsọ̀rí ẹbí àwọn ẹranko tí a mọ̀ sí Bovinae, tí wọ́n wọ́pọ̀ ju màlúù kẹ̀tẹ̀ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.
Ìwúlò Màlúù
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n sábà ma ń rè tàbí sin màlúù gẹ́gẹ́ bí ohun ọ̀sìn fún jíjẹ, pípèsè ẹran, fífi awọ rẹ̀ ṣe pànmọ́, ohun tí a lè fi pèsè wàrà, wọ́n ń lò wọ́n fún kíkọ ebè oko, lílo ìgbẹ́ rẹ̀ fún ajílẹ̀, tí ọ̀pọ̀ níní àwọn ẹ̀yà kan ní ilẹ̀ India ma ń sìn ín gẹ́gẹ́ bí òrìṣà tabí ọlọ́run wọn. [1] According to an estimate from 2011, there are 1.4 billion cattle in the world.[2].[3]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Bollongino, R.; Burger, J.; Powell, A.; Mashkour, M.; Vigne, J.-D.; Thomas, M. G. (2012). "Modern taurine cattle descended from small number of Near-Eastern founders". Molecular Biology and Evolution 29 (9): 2101–2104. doi:10.1093/molbev/mss092. PMID 22422765. Archived from the original on 31 March 2012. https://web.archive.org/web/20120331193505/http://mbe.oxfordjournals.org/content/early/2012/03/14/molbev.mss092. Op. cit. in Wilkins, Alasdair (28 March 2012). "DNA reveals that cows were almost impossible to domesticate". io9. Archived from the original on 12 May 2012. https://web.archive.org/web/20120512072737/http://io9.com/5897169/dna-reveals-that-cows-were-almost-impossible-to-domesticate?tag=archaeology. Retrieved 2 April 2012.
- ↑ "Counting Chickens". The Economist. 27 July 2011. Archived from the original on 15 July 2016. https://web.archive.org/web/20160715181213/http://www.economist.com/blogs/dailychart/2011/07/global-livestock-counts. Retrieved 6 July 2016.
- ↑ Brown, David (23 April 2009). "Scientists Unravel Genome of the Cow". The Washington Post. Archived from the original on 28 June 2011. https://web.archive.org/web/20110628203746/http://www.washingtonpost.com/wp-dyn/content/article/2009/04/23/AR2009042303453.html. Retrieved 23 April 2009.