Oníṣe:Ọmọladéabídèmí99
Jump to navigation
Jump to search
Orúkọ mi ni Ọmọladé Abídèmí; mo jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ èdè Yorùbá ní ilé ìwé gíga Fásitì ìjọba àpapọ̀ tí Ìpínlẹ̀ Èkó ní ilẹ̀ Nàìjíríà. Ìpinnu mi lórí ìwé Wikipedia yìí ni láti ṣe àfikún sí èdè Yorùbá.