The content is as wide as possible for your browser window.
Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
My name is Omolade Dorcas Abidemi, I'm a graduate of Linguistics and Yoruba, from the University of Lagos. I joined Wikipedia in 2019, and I've been an active contributor to the Yoruba Wikipedia ever since then. My passion for contributing to free knowledge in the Yoruba language, love for the promotion and development of the language and as well as my zeal towards keeping the language from going into extinction is one of my major reasons for joining the Wikimedia community.
I am the founder of Yoruba Wikipedia Fan-club in University of Lagos, which was established in 2022.
I am presently the programs officer and Wikipedian-in-Residence, at the International Centre for Yoruba Arts and Culture, Ibadan for the Yorùbá Wikimedians User Group.
I have participated in several contests and I have over 400 articles written in Yoruba language.
I was awarded the Best Indigenous language contributor by the Wikimedian Nigeria User Group in 2024, as a result of my active contributions to a language Wikipedia.
Orúkọ mi ni Ọmọladé Dorcas Abídèmí; mo gboyè B.A nínú ẹ̀kọ́ Lìǹgúísíìkì àti èdè Yorùbá ní ilé ìwé gíga Fásitì ìjọba àpapọ̀ tí Ìpínlẹ̀ Èkó ní ilẹ̀ Nàìjíríà. Mo darapọ̀ mọ́ ìwé ìmọ̀-ọ̀fẹ́ Wikipedia ní ọdún 2019. Ìpinnu mi lórí ìwé ìmọ̀-ọ̀fẹ́ Wikipedia yìí ni láti ṣe àfikún sí èdè Yorùbá. Ìfẹ́ tí mo ní sí èdè Yorùbá, ìgbìyànjú láti gbé èdè náà lárugẹ àti ìtara kí èdè náà má parun ló mú mi darapọ̀ mọ́ Wikipedia.
Èmi ni mo ṣe ìdásílẹ̀ Yorùbá Wikipedia Fan-club ní Unilag, ní ọdún 2022. Lọ́wọ́ lọ́wọ́, èmi ni Wikipedian-in-Residence, ní international for Yorùbá Arts and Culture, ní ìlú Ìbàdàn, fún Yorùbá Wikimedians User Group.