Oníṣe:Oladimeji mayowa

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Emmanuel Iren[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Emmanuel Iren ( ọjọ kejidinlogun osu Kejìlá ọdún 1989) je iransẹ ọlọrun ní ìlú Àdàkọ:Naijiria, Olorin ati Akòwé. ti o tèdó sí ìlú Èkó Ohun sí ni olùṣọ àgùntàn àgbà lori ijọ Celebration church international ijo ti o ni ẹka mẹsan ka kiri agbaye.

Ìbéèrè ayé rẹ[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Emmanuel Iren jẹ ọmọ bíbí ìlú Èkó sinu idile ọgbẹni Emmanuel ati iya afin olubunmi Eruk-Iren.o kẹkọọ gbọye kiko ile lati ile iwe gíga Àdàkọ:Covenant university.

ìṣura paṣipaarọ ti abuja[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

iṣura paṣipaarọ ti Abuja (ASE) a ṣe idasilẹ rẹ ní ọdún 2000 o sí bere isẹ ni ọdún 2001. O jẹ akọkọ nínú exchange ni Naijiria to provide electronic trading, to yanjú ibugbe fún primary market àti secondary markets. A dasilẹ láti s'owo ni awọn inifura, ti ko ni akojọstocks àti itele vanilla bonds.

Laipe ti a fi le'lẹ government iwifunni fi agbára mú láti dá owó iṣẹ dúró. Lati òke wá Nigerian Stock Exchange ti ọ já ijakadi pelu ìjọba lati se abojuto anikanjọpọn lori Nigerian stock markets. Eyi je ìdí tí a fi iwifunni ni wípé ko sí ìdí láti dá ilé ìṣura paṣipaarọ keji silẹ nínú orilẹ ède.


Sibẹsibẹ, ìgbìyànjú tẹsiwaju lati yi awọn ile iṣẹ ti tẹlẹ sí multicommodity exchange commodities exchange.