Onesphore Nzikwinkunda
Ìrísí
Onesphore Nzikwinkunda (ti a bi ni ọjọ kewa osu Okudu ọdun 1997) jẹ elere ije jinjinna ọmọ orilẹ-ede Burundi, ti o nsa ni mita 5K ati 10K . Ni ọdun 2019, o dije ninu mita 10,000 awọn ọkunrin ni Idije Awọn ere-idaraya Agbaye ti 2019 ti o waye ni Doha, Qatar. [1] O pari ni ipo 18th. [1]
Ni ọdun 2017, o dije ninu idije awọn ọkunrin agba ni 2017 IAAF World Cross Country Championship ti o waye ni Kampala, Uganda. [2] O pari ni ipo 14th. [2] Ni ọdun 2019, o dije ninu idije awọn ọkunrin agba ni 2019 IAAF World Cross Country Championships ti o waye ni Aarhus, Denmark. [3] O tun pari ni ipo 14th. [3]
Ni ọdun 2019, o tun ṣe aṣoju orilẹ-ede Burundi ni Awọn ere Afirika 2019 ati pe o pari ni ipo 6th ninu mita 10,000 ọkunrin. [4]
Awọn itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ita ìjápọ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Onesphore Nzikwinkunda at World Athletics