Open Austrálíà 2000 − Àwọn Obìnrin Ẹnìkan
Appearance
Lindas Davensport fi ajulo han Martina Hingis ni eemeta otooto, ti osi gbe igba oroke ninu boolu eleyin alafowogba ori tabili ni awon Obinirin Enikan. Davensport ko fi igba kankan fi di remi ninu tonamenti naa.