Orílẹ̀-èdè olómìnira onímàle
Ìrísí
Orílẹ̀-èdè olómìnira onímàle ni ilẹ̀ aládàáni kan tí ó únlo àwọn òfin onímàle fún ìjọba, ó sì yàtọ̀ sí ilẹ̀ọba onímàle. Fún lílò ní orúkọ, àwọn orílẹ̀-èdè mẹ́rin ló jẹ́ orílẹ̀-èdè olómìnira onímàle. Àwọn wọ̀nyí ni Afghanistan, Iran, Mauritania and Pakistan. Pakistan ló kọ́kọ́ lo orúkọ yìí ní 1956 lábẹ́ òfin-ìbágbepọ̀; Mauritania bẹ̀rẹ̀ sí ní lòó ní 28 November 1958; Iran bẹ̀rẹ̀ sí ní lòó lẹ́yìn Ìjídìde àwọn ará Ìránì 1979 tó gbàjọba lọ́wọ́ Pahlavi dynasty; àti Afghanistan bẹ̀rẹ̀ sí ní lòó ní 2004 lẹ́yìn ìwólulẹ̀ ìjọba Tàlìbánì.
Àtòjọ àwọn orílẹ̀-èdè olómìnira onímàle
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Orílẹ̀-èdè | Ọjọ́ọdún tó bẹ̀rẹ̀ | Irú ìjọba |
---|---|---|
Islamic Republic of Afghanistan
|
7 December 2004 | Unitary presidential republic |
Islamic Republic of Iran | 1 April 1979[1] | Unitary Khomeinist presidential republic (de facto theocratic-republican subject to a Supreme Leader) |
Islamic Republic of Mauritania | 28 November 1960 | Unitary semi-presidential republic |
Islamic Republic of Pakistan | 23 March 1956 | Federal parliamentary constitutional republic |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Iran Islamic Republic". Encyclopædia Britannica. Retrieved 28 December 2019.