Orúkọ Àdúgbò ní Ìjẹ̀bú-Rémo, Ìpínlẹ̀ Ògùn, Nàìjíríà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

ÌJÈBÚ-RÉMO[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Adugbò: Ìkénné Itumò: Kòríkó ìkólé ti a ń pè ní ìken nì èdè Rémo ni ó wópò púpò ní agbegbe kan nì ayé ojoún. Nìgbà ti ó wà dì wí pé awoòn ènìyàn ń gbé abbègbè yìí bí ìlú ni won bá n so wí pé a tun ni ni ikèn néè o. èyí ti a wa se ìsúnkì gbólohùn náà sí ìkènné.


Adugbò: Sònyìndo Itumo: Òkunrìn jagunjagun kan ni àdúgbò yìí ni ó ka ení rè kan mo ibi ti ó tí n kínrin aya re ken leyin nigbati aránbìnrin náà ń wè ní ile iwe. Inu bi okunrin yìí pàápàá nitori pe erúbinrin náà kò sá nìgbà ti é rí ì. Èyí mu kì ó bínu pa ìyàwó rè àti erúbìnrin náà Nìgbà ti won sì bì í ìdí ti ó fi se béè o sàlàyé pé ń se ni erú yìí sànyín-dó. Lati ìgbà náà ni a ti ń pe adugbo ohun ní sànyìndó.

Àdúgbò: Ajíno Itumò: Nì ayé àtijó, òwúrò kùtùkùtù ni won máa ń ná ojà agbègbè kan báyìí ni ìlè Remo. Kèrèkèrè, awon ènìyàn bèrè sí ìlé ní í ko sí ibi ofà yii, wón sì ń gbé ibe. Bayìí ni won se so ojà náà ní Ajino ti àwon ènìyàn sì so adugbo náà nì Ajìwo titi di ìsìnsìnyí.


Adúgbo: Ìmóbìdo Itumò: Agbègbè ti a fi igi Obì pààlà tàbí sàmì sí. Àwon méjì ti ó ń jà du ààlà ilè ni o fa orúko yìí jáde nítorí awon tì ó nì ìlè salàyé wí pé ìgi obì ni àwon fì dó: ìlè àwon láti fi se idámo sí ilè elòmìíràn.

Adúgbò: Ìdótun Itumò: Ní asìko ogun ti awon Yorùbá ń ti ibi kan dé ibì kan ni àwon kan ko ara won jò láti te ìlú tìtun dó. Léyin ti awon ènìyàn ti n pò níbe ni wòn wa so ìbùdó won yìí ní ‘Ìdótùn’ èyí ti ó túmò sí ibùdó tìtun.

Àdùgbò: Ìdómolè Itumò: Nítorí àgbára àti ìwa ìpàǹle tàbí ìwà jàgídíjàgan okunrin kan báyìí ti a pe orùko rè ní Ìdó ni àsìkò Ojoun ni a se so oruko adugbo yìí ní Ìdómolè léyìn ikù okunrin yìí ni awon ènìyàn bérè sì fi okunrin yìí júwè adúgbò ré. Won a ní awon n lo sí Ìdó akínkayú nì tàbí okùnrin imolè nì. Báyìí ni a kuku so adúgbà di Ìdómolè.

Àdùgbó: Ìròlù Ìtumò: Léyìn ìgbà ti awon Yorùbá ken ti gbà latí parapò máa gbe pèlu ìrépò ni agbègbè kémo, yìí ni won kùkú wá pè è ní Ìrolù. Èyí túmo sì pé awon jo kò ó lù ni kí àwón tó ‘péjo síbè.

Àdugbò: Sáàpàdé Itumò: Àwon ìlu méta ni ó parapò sí ojú kan. Nígbà tí ó wà di wì pé okan kò yòǹda oruko tirè oún èkèjì ni wón wà yo nínú oruko awon meteeta; làti yo sàaàpàde Ìsarà – láti ibi ni wón ti yo ‘sá’ Ìparà – láti ibi ni wón ti yo oá’ Odè – láti ibi ni wón ti yo dé’ Àpaofò sá- pà-dé ni ó wá di sápadè.

Àdúgbò: Ìsarà Itúmò: Òde nì awon tí ó parapò te ìlú ìsara dó. Kaluku awon ènìyàn wònyi ni won sì wá láti agbègbè òtòòtó. Nígbà ti ó wá dì wí pè ènìkan fé so ara re di olorí ‘àpàpàndodo ni won bá làá yée pe n se nì awon sa ara awon jo sibe! Ti won sì ‘sun orúkò náà kì di Isarà.


Àdugbò: Ògèrè Ìtumò: Áwon tí ó ń gbé òkèèrè ni won ti kèrèkèrè só dì ògèrè. Láyé àtijó bì ó bà ti dì wí pé awon ènìyàn Remo bà fé lo sí ibi ti awon are ‘Ògèrè wá won a so wí pè awon fe ló sí agbègbè awon ara òkèèrè. Awon ènìyàn wònyí búrú púpò jù, won sì taari won sìwaju. Won á ni Okeere ni ó ye won. Nígbà ti ójú ń là nì wón bà so oruko ìlú yìí di Ògèrè.

Àdúgbò: Ajítaádùn Itùmò: Ìyá kan wà tí ó ń gbe àdúgbò yìí ni ayé ojoun. Kó sì ìgbà ti àwon ènìyàn dé òdò rè tí kìí ni oúnje àdi`dùn. Nìgbà ti ò dì wí pe gbogbo ènìyàn bere si fi ounje ìyà yìí júwè adúgbò naa ni wòn kúkú wa n pe adugbo yìí ní Ajítáádùn (Ají-ta-dídùn).

(see Yoruba Place Names)