Jump to content

Orin ọdún ń lọ sópin

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Orin Ọdún ń lọ sópin ni orin tí ẹgbẹ́ akọrin Obìnrin rere ti ìjọ C.A.C gbé jáde lábẹ́ ìdarí Dèbórà Adébọ́lá Fáṣọyin lọ́dun 1979. Orin 'ọdún ń lọ sópin' yí jẹ́ orin tí wọ́n fi èdè Yorùbá gbé jáde, tí ó sì rìnlẹ̀ gidigidi. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn lò ma ń lo orin yí gẹ́gẹ́ bí orin àdúrà láti fi ṣe ìpalẹ̀mọ́ fún ọdún tuntun. [1]

Àkójọpọ̀ àwọn akọrin náà

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn akópa nínú orin yí nígbà náà jẹ́ Mẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n (35), tí wọ́n sì ti dín kù sí Méjìlá (12) látàrí bí ikú ṣe ń mú wọn lẹ́yọ kọ̀ọ̀kàn. [2] [3]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "The Shuffle: 'Tis the season for CAC Good Women Choir's "Odun lo sopin" classic". The Native. 2019-09-02. Retrieved 2019-12-31. 
  2. Tayo, Ayomide O. (2017-12-10). "The story of the CAC Good Women Choir and the evergreen song". Pulse Nigeria. Retrieved 2019-12-31. 
  3. "Odun Nlo Sopin Part 1". Spotify. 2012-02-26. Retrieved 2019-12-31.